Prayer Points For Today

PRAY WITH (PSALM 119; 144; EPHESIANS 6)

1. I thank You for teaching my hand to war and my fingers to fight.

2 . Lord, I thank You for I am out of captivity by fire.
3 . Blood of Jesus, purify me now in Jesus' name.
4 . Destiny vandalizers, begin to destroy yourselves in Jesus' name.
5. God of mercy, save my family from the wrath to come in Jesus' name.
6. Daddy, visit me and rewrite my story.
7. You spirit of ancestors sitting on my children, be unseated by fire.
8. Every illegal occupants in my business, I reject you by fire.
9 . Grace to study the Word of God, possess me.
10. I receive grace to restitute my ways in Jesus' name.
11. Those I am leading shall not lead me into sin in Jesus' name.
12. Lord, give me the grace to obey You rather than men in Jesus' name.

KOKO ADURA FUN 13/07/20 GBADURA PELU ORIN DAFIDI 119; 144; EFESU 6
1. Modupe l'owo Re pe O nko owo mi lati jagun ati ika mi lati ja.
2. Oluwa, modupe lowo Re tori wipe mo ti jade kuro ninu igbekun nipa ina.
3 . Eje Jesu, fo mi mo lati isinsiyi ni oruko Jesu.
4 . Eyin emi apa ayanmo, e bere si ni pa ara yin ni oruko Jesu.
5 . Olorun Aanu, gba ebi mi kuro ninu ibinu to nbo ni oruko Jesu.
6. Baba, be mi wo ki O si tun itan aiye mi ko.
7. Eyin emi baba nla ti o joko le awon omo mi l'ori, e sidi
nipa ina.
8. Gbogbo alejo okunkun ninu ise mi, mo ko yin nipa ina.
9. Ore-ofe lati ma saapon ninu Oro Olorun, gbe mi wo.
10. Mo gba ore-ofe lati se atunse si awon ona mi l’oruko Jesu.
11. Awon ti mo ndari ki yio dari mi sinu ese ni oruko Jesu.
12. Oluwa, fun mi ni ore-ofe lati gbonran si ase Re dipo ase eniyan ni oruko Jesu.

Your Friend

Post a Comment

0 Comments